Ìṣe Àwọn Aposteli 1:9 BM

9 Nígbà tí ó ti sọ báyìí tán, bí wọ́n ti ń wò ó, a gbé e sókè, ìkùukùu bò ó, wọn kò sì rí i mọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 1

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 1:9 ni o tọ