Ìṣe Àwọn Aposteli 10:30 BM

30 Kọniliu dáhùn pé, “Ní ijẹrin, ní déédé àkókò yìí, mo ń gbadura ninu ilé mi ní agogo mẹta ọ̀sán. Ọkunrin kan bá yọ sí mi, ó wọ aṣọ dídán.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:30 ni o tọ