Ìṣe Àwọn Aposteli 10:36 BM

36 Ẹ mọ iṣẹ́ tí ó rán sí àwọn ọmọ Israẹli, ọ̀rọ̀ ìyìn rere alaafia nípasẹ̀ Jesu Kristi, ẹni tíí ṣe Oluwa gbogbo eniyan.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:36 ni o tọ