Ìṣe Àwọn Aposteli 10:4 BM

4 Kọniliu bá tẹjú mọ́ ọn. Ẹ̀rù bà á, ó ní, “Kí ló dé, alàgbà?”Angẹli yìí bá sọ fún un pé, “Adura rẹ ti gbà; iṣẹ́ àánú rẹ ti gòkè lọ siwaju Ọlọrun. Ọlọrun sì ti ranti rẹ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 10

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 10:4 ni o tọ