13 Ó sọ fún wa bí òun ti ṣe rí angẹli tí ó dúró ninu ilé òun tí ó sọ pé, ‘Ranṣẹ lọ sí Jọpa, kí o pe Simoni tí àpèlé rẹ̀ ń jẹ́ Peteru wá.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 11
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 11:13 ni o tọ