Ìṣe Àwọn Aposteli 11:16 BM

16 Ó mú mi ranti ọ̀rọ̀ Oluwa nígbà tí ó sọ pé, ‘Omi ni Johanu fi ṣe ìwẹ̀nùmọ́ fun yín, ṣugbọn Ẹ̀mí Mímọ́ ni a óo fi ṣe ìwẹ̀nùmọ́ yín.’

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 11:16 ni o tọ