Ìṣe Àwọn Aposteli 11:19 BM

19 Àwọn tí ó túká nígbà inúnibíni tí ó ṣẹlẹ̀ ní àkókò Stefanu dé Fonike ní Kipru ati Antioku. Wọn kò bá ẹnikẹ́ni sọ̀rọ̀ ìyìn rere àfi àwọn Juu nìkan.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 11:19 ni o tọ