Ìṣe Àwọn Aposteli 11:21 BM

21 Agbára Oluwa hàn ninu iṣẹ́ wọn. Ọpọlọpọ eniyan ni wọ́n gbàgbọ́, tí wọ́n sì yipada sí Oluwa.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 11

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 11:21 ni o tọ