Ìṣe Àwọn Aposteli 12:4 BM

4 Ó bá mú Peteru ó tì í mọ́lé. Ó fi í lé àwọn ọ̀wọ́ ọmọ-ogun mẹrin lọ́wọ́ láti máa ṣọ́ ọ; (ọmọ-ogun mẹrin ni ó wà ní ọ̀wọ́ kọ̀ọ̀kan). Hẹrọdu fẹ́ mú Peteru wá siwaju gbogbo eniyan fún ìdájọ́ lẹ́yìn Àjọ̀dún Ìrékọjá.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 12

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 12:4 ni o tọ