Ìṣe Àwọn Aposteli 13:1 BM

1 Àwọn wolii ati àwọn olùkọ́ wà ninu ìjọ tí ó wà ní Antioku. Ninu wọn ni Banaba ati Simeoni tí wọn ń pè ní Adúláwọ̀ wà, ati Lukiusi ará Kirene, ati Manaeni tí wọ́n jọ tọ́ dàgbà pẹlu Hẹrọdu baálẹ̀, ati Saulu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 13:1 ni o tọ