Ìṣe Àwọn Aposteli 13:17 BM

17 Ọlọrun àwọn eniyan yìí, eniyan Israẹli, yan àwọn baba wa. Nígbà tí wọn ń gbé ilẹ̀ Ijipti bí àlejò, Ọlọrun sọ wọ́n di eniyan ńlá. Ó fi agbára ńlá rẹ̀ hàn nígbà tí ó mú wọn jáde kúrò ní Ijipti.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 13:17 ni o tọ