45 Nígbà tí àwọn Juu rí ọ̀pọ̀ eniyan, owú mú kí inú bí wọn. Wọ́n bá ń bu ẹnu àtẹ́ lu ohun tí Paulu ń sọ; wọ́n ń sọ ìsọkúsọ sí wọn.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 13:45 ni o tọ