50 Ṣugbọn àwọn Juu rú àwọn gbajúmọ̀ obinrin olùfọkànsìn sókè, ati àwọn eniyan pataki-pataki ní ìlú, ni wọ́n bá ń ṣe inúnibíni sí Paulu ati Banaba. Wọ́n lé wọn jáde kúrò ní agbègbè wọn.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 13
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 13:50 ni o tọ