Ìṣe Àwọn Aposteli 14:19 BM

19 Ṣugbọn àwọn Juu dé láti Antioku ati Ikoniomu, wọ́n yí ọkàn àwọn eniyan pada, wọ́n sọ Paulu ní òkúta, wọ́n sì wọ́ ọ lọ sẹ́yìn odi, wọ́n ṣebí ó ti kú.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 14:19 ni o tọ