Ìṣe Àwọn Aposteli 14:21 BM

21 Wọ́n waasu ìyìn rere ní ìlú náà, àwọn eniyan pupọ sì di onigbagbọ. Wọ́n bá pada sí Listira ati Ikoniomu ati Antioku ní Pisidia.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 14

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 14:21 ni o tọ