16 ‘Lẹ́yìn èyí, n óo tún ilé Dafidi tí ó ti wó kọ́.N óo tún ahoro rẹ̀ mọ,n óo sì gbé e ró.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 15
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 15:16 ni o tọ