Ìṣe Àwọn Aposteli 15:25 BM

25 A ti wá pinnu, gbogbo wa sì fohùn sí i, a wá yan àwọn eniyan láti rán si yín pẹlu Banaba ati Paulu, àwọn àyànfẹ́ wa,

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 15:25 ni o tọ