Ìṣe Àwọn Aposteli 15:31 BM

31 Nígbà tí wọ́n kà á, inú wọn dùn sí ọ̀rọ̀ ìyànjú tí ó wà ninu rẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 15:31 ni o tọ