Ìṣe Àwọn Aposteli 15:38 BM

38 Ṣugbọn Paulu kò rò pé ó yẹ láti mú un lọ, nítorí ó pada lẹ́yìn wọn ní Pamfilia, kò bá wọn lọ títí dé òpin iṣẹ́ náà.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 15:38 ni o tọ