Ìṣe Àwọn Aposteli 15:5 BM

5 Àwọn kan láti inú ẹgbẹ́ àwọn Farisi tí wọ́n jẹ́ onigbagbọ wá dìde. Wọ́n ní, “Dandan ni pé kí á kọ àwọn tí kì í ṣe Juu tí ó bá fẹ́ di onigbagbọ nílà, kí á sì pàṣẹ fún wọn láti máa pa Òfin Mose mọ́.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 15

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 15:5 ni o tọ