Ìṣe Àwọn Aposteli 16:24 BM

24 Nígbà tí ó ti gba irú àṣẹ báyìí, ó sọ wọ́n sinu àtìmọ́lé ti inú patapata, ó tún fi ààbà kan ẹsẹ̀ wọn mọ́ igi.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 16

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 16:24 ni o tọ