29 Ẹni tí ń ṣọ́ ilé ẹ̀wọ̀n náà bá bèèrè iná, ó pa kuuru wọ inú iyàrá, ó ń gbọ̀n láti orí dé ẹsẹ̀. Ó wólẹ̀ níwájú Paulu ati Sila.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 16
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 16:29 ni o tọ