6 Wọ́n gba ilẹ̀ Firigia ati Galatia kọjá. Ẹ̀mí Mímọ́ kò gbà wọ́n láàyè láti lọ waasu ọ̀rọ̀ Oluwa ní Esia.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 16
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 16:6 ni o tọ