10 Nígbà tí ilẹ̀ ṣú, àwọn onigbagbọ tètè ṣe ètò láti mú Paulu ati Sila lọ sí Beria. Nígbà tí wọ́n dé ibẹ̀, wọ́n lọ sí ilé ìpàdé àwọn Juu.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 17:10 ni o tọ