Ìṣe Àwọn Aposteli 17:19 BM

19 Ni wọ́n bá ní kí ó kálọ sí Òkè Areopagu. Wọ́n wá bi í pé, “Ǹjẹ́ a lè mọ ohun tí ẹ̀kọ́ titun tí ò ń sọ̀rọ̀ rẹ̀ yìí jẹ́?

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 17

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 17:19 ni o tọ