Ìṣe Àwọn Aposteli 18:10 BM

10 Nítorí n óo wà pẹlu rẹ. Kò sí ẹni tí yóo fọwọ́ kàn ọ́ láti ṣe ọ́ níbi. Nítorí mo ní eniyan pupọ ninu ìlú yìí.”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:10 ni o tọ