21 Bí ó ti fẹ́ kúrò lọ́dọ̀ wọn, ó ní, “N óo tún pada wá sí ọ̀dọ̀ yín bí Ọlọrun bá fẹ́.” Ó bá kúrò ní Efesu.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:21 ni o tọ