23 Ó dúró níbẹ̀ fún ìgbà díẹ̀. Ó bá tún kúrò, ó la agbègbè Galatia ati ti Firigia já, ó ń mú gbogbo àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu lọ́kàn le.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:23 ni o tọ