3 Nítorí pé iṣẹ́ kan náà ni wọ́n ń ṣe, Paulu lọ wọ̀ lọ́dọ̀ wọn, ó sì ń ṣiṣẹ́. Iṣẹ́ ọnà awọ tí wọ́n fi ń ṣe àgọ́ ni wọ́n ń ṣe.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 18
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 18:3 ni o tọ