1 Nígbà tí Apolo wà ní Kọrinti, Paulu gba ọ̀nà ilẹ̀ la àwọn ìlú tí ó wà ní àríwá Antioku kọjá títí ó fi dé Efesu. Ó rí àwọn ọmọ-ẹ̀yìn Jesu mélòó kan níbẹ̀.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 19
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 19:1 ni o tọ