10 Báyìí ló ṣe fún ọdún meji, tí ó fi jẹ́ pé gbogbo àwọn tí ń gbé Esia: ati Juu ati Giriki, ni ó gbọ́ ọ̀rọ̀ Oluwa.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 19
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 19:10 ni o tọ