Ìṣe Àwọn Aposteli 19:28 BM

28 Nígbà tí wọ́n gbọ́, inú bí wọn pupọ. Wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí kígbe, wọ́n ń wí pé, “Oriṣa ńlá ni Atẹmisi, oriṣa àwọn ará Efesu!”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 19:28 ni o tọ