Ìṣe Àwọn Aposteli 19:6 BM

6 Nígbà tí Paulu gbé ọwọ́ lé wọn, Ẹ̀mí Mímọ́ bà lé wọn, wọ́n bá bẹ̀rẹ̀ sí fi èdè mìíràn sọ̀rọ̀, wọ́n ń sọ àsọtẹ́lẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 19

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 19:6 ni o tọ