11 àwọn Juu ati àwọn aláwọ̀ṣe ẹ̀sìn Juu; àwọn ará Kirete ati àwọn ará Arabia, gbogbo wa ni a gbọ́ tí wọ́n ń sọ àwọn iṣẹ́ ńlá Ọlọrun ní oríṣìíríṣìí èdè wa.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:11 ni o tọ