Ìṣe Àwọn Aposteli 2:22 BM

22 “Ẹ̀yin ará, ọmọ Israẹli, ẹ fetí sí ọ̀rọ̀ mi. Jesu ará Nasarẹti ni ẹni tí Ọlọrun ti fihàn fun yín pẹlu iṣẹ́ agbára, iṣẹ́ ìyanu, iṣẹ́ abàmì tí Ọlọrun ti ọwọ́ rẹ̀ ṣe láàrin yín. Ẹ̀yin fúnra yín sì mọ̀ bẹ́ẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:22 ni o tọ