26 Nítorí náà inú mi dùn, mo bú sẹ́rìn-ín.Bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé eniyan ẹlẹ́ran-ara ni mí,sibẹ n óo gbé ìgbé-ayé mi pẹlu ìrètí;
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:26 ni o tọ