3 Wọ́n rí nǹkankan tí ó dàbí ahọ́n iná, tí ó pín ara rẹ̀, tí ó sì bà lé ẹnìkọ̀ọ̀kan wọn.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:3 ni o tọ