Ìṣe Àwọn Aposteli 2:41 BM

41 A ṣe ìrìbọmi fún àwọn tí wọ́n gba ọ̀rọ̀ náà. Ní ọjọ́ náà àwọn ẹgbẹẹdogun (3,000) eniyan ni a kà kún ọmọ ìjọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:41 ni o tọ