Ìṣe Àwọn Aposteli 2:46 BM

46 Wọ́n ń fi ọkàn kan lọ sí Tẹmpili lojoojumọ. Wọ́n jọ ń jẹun láti ilé dé ilé. Wọ́n jọ ń jẹun pẹlu ayọ̀ ati pẹlu ọkàn kan.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 2

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 2:46 ni o tọ