Ìṣe Àwọn Aposteli 20:13 BM

13 A bọ́ siwaju, a wọkọ̀ ojú omi lọ sí Asọsi. Níbẹ̀ ni a lérò pé Paulu yóo ti wá bá wa tí òun náà yóo sì wọkọ̀. Òun ló ṣe ètò bẹ́ẹ̀ nítorí ó fẹ́ fẹsẹ̀ rìn dé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:13 ni o tọ