Ìṣe Àwọn Aposteli 20:16 BM

16 Nítorí Paulu ti pinnu láti wọkọ̀ kọjá Efesu, kí ó má baà pẹ́ pupọ ní Esia, nítorí ó ń dàníyàn pé bí ó bá ṣeéṣe, òun fẹ́ ṣe Àjọ̀dún Pẹntikọsti ní Jerusalẹmu.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:16 ni o tọ