19 Ẹ mọ̀ bí mo ti fi ìrẹ̀lẹ̀ ati omi ojú sin Oluwa ní ọ̀nà gbogbo ninu àwọn ìṣòro tí mo fara dà nítorí ọ̀tẹ̀ tí àwọn Juu dì sí mi.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:19 ni o tọ