Ìṣe Àwọn Aposteli 20:32 BM

32 “Nisinsinyii, mo fi yín lé Ọlọrun lọ́wọ́ ati ọ̀rọ̀ oore-ọ̀fẹ́ rẹ̀ tí ó lè mu yín dàgbà, tí ó sì lè fun yín ní ogún pẹlu gbogbo àwọn tí a ti sọ di mímọ́.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:32 ni o tọ