Ìṣe Àwọn Aposteli 20:35 BM

35 Mo ti fihàn yín pé bẹ́ẹ̀ ni a níláti ṣiṣẹ́ láti ran àwọn aláìlera lọ́wọ́. Kí á máa ranti àwọn ọ̀rọ̀ Oluwa Jesu, nítorí òun fúnra rẹ̀ sọ pé, ‘Ayọ̀ pọ̀ ninu kí a máa fúnni ní nǹkan ju kí á máa gbà lọ.’ ”

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 20

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 20:35 ni o tọ