Ìṣe Àwọn Aposteli 21:1 BM

1 Nígbà tí a dágbére fún wọn tán, ọkọ̀ ṣí. A wá lọ tààrà sí Kosi. Ní ọjọ́ keji a dé Rodọsi. Láti ibẹ̀ a lọ sí Patara.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:1 ni o tọ