13 Ṣugbọn Paulu dáhùn pé, “Kí ló dé tí ẹ̀ ń sunkún, tí ẹ̀ ń mú ìrẹ̀wẹ̀sì ọkàn bá mi? Mo ti múra ẹ̀wọ̀n ati ikú pàápàá ní Jerusalẹmu nítorí orúkọ Oluwa Jesu.”
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:13 ni o tọ