19 Nígbà tí Paulu kí wọn tán, ó ròyìn lẹ́sẹẹsẹ iṣẹ́ tí Ọlọrun lo òun láti ṣe láàrin àwọn tí kì í ṣe Juu.
Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 21
Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 21:19 ni o tọ