Ìṣe Àwọn Aposteli 22:19 BM

19 Mo dáhùn, mo ní, ‘Oluwa, àwọn gan-an mọ̀ pé èmi ni mo máa ń sọ àwọn tí ó bá gbà ọ́ gbọ́ sẹ́wọ̀n, tí mo sì máa ń nà wọ́n káàkiri láti ilé ìpàdé kan dé ekeji.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 22:19 ni o tọ