Ìṣe Àwọn Aposteli 22:4 BM

4 Mo ṣe inúnibíni sí ọ̀nà ẹ̀sìn yìí. Gbogbo àwọn tí ń tẹ̀lé Jesu ni mò ń lé kiri: ẹni tí mo bá sì bá ninu wọn pípa ni. Èmi a mú wọn, èmi a dè wọ́n, wọn a sì sọ wọ́n sẹ́wọ̀n, atọkunrin atobinrin wọn.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 22

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 22:4 ni o tọ