Ìṣe Àwọn Aposteli 23:10 BM

10 Nígbà tí àríyànjiyàn náà pọ̀ pupọ, ẹ̀rù ba ọ̀gágun pé kí wọn má baà fa Paulu ya. Ó bá pàṣẹ fún àwọn ọmọ-ogun kí wọn wá fi agbára mú Paulu kúrò láàrin wọn, kí wọn mú un wọnú àgọ́ àwọn ọmọ-ogun lọ.

Ka pipe ipin Ìṣe Àwọn Aposteli 23

Wo Ìṣe Àwọn Aposteli 23:10 ni o tọ